Recent Posts

To’Ju Iwa Re, Ore Mi 

To’ju iwa re, ore mi, Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia. Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola, Okun l’ola, okun n’igbi oro,   Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ni de sare’e, Owo ko je nkan fun ni. …

Read More »

Oriki Obinrin Yoruba

Obinrin ni aya okunrin, Obinrin ni iya okunrin Okunrin a ma lagbara sugbon obinrin a ma l’ete Ete si niyi, ni iwon ju agbara lo Ni won ma fi ni wipe Okunrin ti obinrin o le mu, iyen ti mi tan l’atano Obinrin a pa eje modi, atun fidi le …

Read More »